Ɛ KÁÁBƆ̀ SÍ INƆ́N ƆGBÀ ÈDÈ ÀNÀGÓ TÓ Í GBÉGA
ÌSHE ÀTI ÀSHÀ
ÈDÈ ABÍNIBÍ
ÌTÚMÀN
ÌDÀGBÀSÓKÈ ƆMƆ ÌLÚ
Ɔ̀RƆ̀ ÌSHÍWÁJÚ U ALÁGA ƐGBƐ́
Ɔlɔhun maa nbá àwan ònìyàn sɔ ɔ̀rɔ̀ ínán èdè wan bí ònìyàn bá má gbánràn sí Ɔlɔhun ɔ́ gbɔ́dò kɔ́ ìkpi wán ma ngbɔ́ ɔmɔlàkéjì àti ihun ìyé ɔ́ nílò á ti fu gbo ìyanjú sí ikpa ɛ̀mí mímán.
Ishɛ́ wa li gbígbo ìgbàlà àti ìdàgbàsókè fú àwan ònìyàn. Ɔlɔhun ndúró de gbogbo wa fú ishɛ́ nán.
Kó tó ndúró dè áti darankpò mán wa ítoríkperí ishɛ́ ɔ̀fɛ́ kàn ò sí ɔ́dɔ̀ Ɔlɔhun
ojo ò sí ínán ìfɛ́, àmán ìfɛ́ man nlé ojo ítorí kperí ìjìyà lí ojo, oni ìyé ba sì nshe ojo ò kpé ínán ìfɛ́.
Eri aaye ikani ye iyin a ba awan ihun iye ɔda kpade
Ishe ati asha
idagbasoke ɔmɔ ilu
kikɔ ede abinibi
Verset du jour
L’ange lui dit: Ne crains point, Marie; car tu as trouvé grâce devant Dieu. Et voici, tu deviendras enceinte, et tu enfanteras un fils, et tu lui donneras le nom de Jésus.
Luc 1.30