ÌTAN BÍBÉLÌ Í ÈDÈ ÀNÀGÓ:
Ɛ gbɔ́ itàn ogú ínán ìwé e Lúkù bɛ̀rɛ̀ áti erí èkéní títí dé erí ɛ̀kɛ́fà.
Ìtàn Luku àkɔ́kɔ́: | Ìtàn iwe Luku èkéjì | Ìtàn iwe Luku ɛ̀kɛ́ta | Ìtàn iwe Luku ɛ̀kɛ́rin | Ìtàn iwe Luku àkáru | Ìtàn iwe Luku ɛ̀kɛ́fà | Ìtàn iwe Luku èkéje | Ìtàn iwe Luku ɛ̀kɛ́jɔ | Ìtàn iwe Luku èkèsan | Ìtàn iwe Luku ɛ̀kɛ́wa | Ìtàn iwe Luku ɛ̀kɛ́kànlá | Ìtàn iwe Luku èkéjìlá | Ìtàn iwe Luku ɛ̀kɛ́tàlá | Ìtàn iwe Luku ɛ̀kɛ́rìnlá | Ìtàn iwe Luku ɛ̀kɛ́ɛ̀dógú | Ìtàn iwe Luku ɛ̀kɛ́rìndínógú | Itan iwe Luku: ɛ̀kɛ́tàdínógú | Ìtàn iwe Luku èkéjìdínógú | Ìtàn iwe Luku ɛ̀kɛ́kàndínógú | Ìtàn iwe Luku ogú
Ɛ gbɔ́ ìtàn mɛ́wa ínán ìwé e Lúkù áti erí èkéje dé erí ɛ̀kɛ́jɔ.
Ìtàn ìwé Luku ɛ̀kɔ́kànlélógú. | Ìtàn ìwé Luku èkéjìlélógú | Ìtàn ìwé Luku ɛ̀kɛ́tàlélógú | Ìtàn ìwé Luku ɛ̀kɛ́rìnlélógú | Ìtán ìwé Luku kɛ́ɛdɔ́gbɔ̀n | Ìtàn ìwé Luku ɛ̀kɛ́rìndìnɔ́gbòn | Ìtàn ìwé Luku ɛ̀kɛ́tàdínógú. | Ìtàn ìwé Luku èkéjìdínɔ́gbòn | Ìtàn ìwé Luku ɔ̀kɔ́kàndínógú | Ìtàn ìwé Luku ɔgbón
Ɛ gbɔ́ ìtàn mɛ́wa ínán ìwé e Lúkù áti erí èkésan dé erí ɔ̀kɔ́kɔ̀lá.
Ìtàn iwe Luku ɛ̀kɛ́kànlélɔ́gbòn: Àwan ònìyàn nsɔ íkpa oni yé Jésu jɛ́. | Ìtàn ìwé Luku èkéjìlélɔ́gbòn: Jésu f'ara hàn ínán ògo rɛ. | Ìtàn ìwé Luku ɛ̀kɛ́tàlélógbòn: Jésu wo ɔmɔ ɔkɔ̀rin kàn y'ɔ̀ ní ɛ̀mí àyìmán sàn. | Ìtàn ìwé Luku ɛ̀kɛ́rìnlélógbòn: Kí li àwan yé ntɔ Jésu éyìn jɔ? | Ìtán ìwé Luku kárùlélɔ́gbɔ̀n: Jésu fu àwan ɔmɔ èyìn méjìlá rɛ ránshɛ́. | Ìtàn ìwé Luku ɛ̀kɛ́rìndìnógójì: Ará Samaria kàn fu àkpɛrɛ dáadáa hàn. | Ìtàn ìwé Luku ɛ̀kɛ́tàdínógójì: Maata ati Maria gbàlejò́ o Jésu s'ílé wan. | Ìtàn ìwé Luku èkéjìdínógójì: Jésu kɔ́ àwan ɔmɔ èyìn rɛ wan íkpi wán ma ngbàdúrà sí. | Ìtàn ìwé Luku ɔ̀kɔ́kàndínógojí: Jésu nsh'ɛ̀kɔ́ íkpa àwan ɛ̀mí àyìmán. | Ìtàn ìwé Luku ogójì: Jésu sh'ɛ̀kɔ́ kperí inón ònìyàn ló she kpàtàkì kɔ̀ jɛ́ ojú rɛ.
Ɛ gbɔ́ ìtàn mɛ́wa ínán ìwé e Lúkù áti erí èkéjìlá dé erí ɛ̀kɛ́rìnlá.
Itan iwe Luku ɛ̀kɛ́kànlélógójì: Jésu kpe àwan ɔmɔ èyìn rɛ wan s'àkíyèsí á sì mú okàn wan le. | Ìtàn ìwé Luku èkéjìlélógójì: Jésu kìlɔ̀ f'ɔ́mɔ èyìn rɛ wan kperí fú wan má ní ojúkòkòrò. | Ìtàn ìwé Luku ɛ̀kɛ́tàlélógójì: Gbígbé okàn lé Ɔlɔhun í gbogbo ònàn. | Ìtàn ìwé Luku ɛ̀kɛ́rìnlélógójì: Awan ɔmɔ eyin Jésus gbɔdɔ wa i akiyesi... | Ìtàn ìwé Luku àkárùlélógójì: Jésu kìlɔ̀ fú àwan ònìyàn kperí fú wan ro inón kpa ìwà dà. | Ìtán ìwé Luku ɛ̀kɛ́rìndínáàdɔ́ta: Jésu wo arɔ kàn sàn í ijɔ́ ìsimi àwan Júù. | Ìtàn ìwé Luku ɛ̀kɛ́tadìnáàdɔ́ta: Jésu fu ìjɔba Ɔlɔhun wé irúgbìn. | Ìtàn ìwé Luku èkéjìdínàádɔ́ta: Jésu she ìkìlɔ̀ kperí; ó n'ira áti wɔ ìjɔba Ɔlɔhun. | Ìtàn ìwé Luku ɔ̀kɔ́kàndínɔ́gbòn : Jésus fu baálɛ̀ Héródù i èsì ... | Ìtàn ìwé Luku àádɔ́ta : Jésu jɛun í ilé Farisí kàn.